(Verse 1)
Shebi tele tele, lama forh fun won wipe k’oma eas l’oru toripe awa ti (?)Sugbon nisin yi, ton ba wa losan, ton ba wa loru, awa n be ni be, awa o de le forh fun won toripe awa tingasa a o de le sa fun won
(Chorus)
Aye yi o le o, aye lo m’aye le, ninu aye lo ti di f’aye, Aye yi o le o, aye lo m’aye le, ninu aye lo ti di f’aye, ayi yi o ma le o
(Verse 2)
O n pe oku iya e ni, eyin le ma sin iya yin, oku iya omo, eyin le ma sin iya yin
Oku yo si yin, eyin le ma sin iya yin, oku yo (?), eyin le ma sin iya yin
Nigba tin jale, tin ba teni kan je, ti mo ni tire ma da, (?)
(Chorus)
Aye yi o le o, aye lo m’aye le, ninu aye lo ti di f’aye, Aye yi o le o, aye lo m’aye le, ninu aye lo ti di f’aye, ayi yi o ma le o